orí

  1. 1
  2. 2
  3. 3
  4. 4
  5. 5
  6. 6
  7. 7
  8. 8
  9. 9
  10. 10
  11. 11
  12. 12
  13. 13
  14. 14
  15. 15
  16. 16
  17. 17
  18. 18
  19. 19
  20. 20
  21. 21
  22. 22
  23. 23
  24. 24
  25. 25
  26. 26
  27. 27
  28. 28
  29. 29
  30. 30
  31. 31
  32. 32
  33. 33
  34. 34
  35. 35
  36. 36
  37. 37
  38. 38
  39. 39
  40. 40
  41. 41
  42. 42
  43. 43
  44. 44
  45. 45
  46. 46
  47. 47
  48. 48
  49. 49
  50. 50
  51. 51
  52. 52
  53. 53
  54. 54
  55. 55
  56. 56
  57. 57
  58. 58
  59. 59
  60. 60
  61. 61
  62. 62
  63. 63
  64. 64
  65. 65
  66. 66
  67. 67
  68. 68
  69. 69
  70. 70
  71. 71
  72. 72
  73. 73
  74. 74
  75. 75
  76. 76
  77. 77
  78. 78
  79. 79
  80. 80
  81. 81
  82. 82
  83. 83
  84. 84
  85. 85
  86. 86
  87. 87
  88. 88
  89. 89
  90. 90
  91. 91
  92. 92
  93. 93
  94. 94
  95. 95
  96. 96
  97. 97
  98. 98
  99. 99
  100. 100
  101. 101
  102. 102
  103. 103
  104. 104
  105. 105
  106. 106
  107. 107
  108. 108
  109. 109
  110. 110
  111. 111
  112. 112
  113. 113
  114. 114
  115. 115
  116. 116
  117. 117
  118. 118
  119. 119
  120. 120
  121. 121
  122. 122
  123. 123
  124. 124
  125. 125
  126. 126
  127. 127
  128. 128
  129. 129
  130. 130
  131. 131
  132. 132
  133. 133
  134. 134
  135. 135
  136. 136
  137. 137
  138. 138
  139. 139
  140. 140
  141. 141
  142. 142
  143. 143
  144. 144
  145. 145
  146. 146
  147. 147
  148. 148
  149. 149
  150. 150

Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdúrà Fún Ìrànlọ́wọ́ Kúrò Lọ́wọ́ Àwọn Aláìwà-bí-Ọlọ́run

1. Ràn wá lọ́wọ́, Olúwa nítorí ẹni ìwà bí Ọlọ́run kò sí mọ́;Olótìítọ́ tí pòórá kúrò láàrin àwọn ènìyàn.

2. Olúkúlùkù ń parọ́ fún aládùúgbò rẹ̀;ètè èké wọn ń sọ ẹ̀tàn.

3. Kí Olúwa kí ó gé ètè èké wọnàti gbogbo ahọ́n ìfọ́nnu

4. tí ó wí pé, “Àwa ó borí pẹ̀lú ahọ́n wa;àwa ní ètè wa: ta ni ọ̀gá wa?”

5. “Nítorí ìnilára àwọn aláìlágbáraàti ìkéróra àwọn aláìní,Èmi yóò dìde nísinsin yìí” ni Olúwa wí.“Èmi yóò dáàbò bò wọ́n lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe àrankàn wọn”

6. Ọ̀rọ̀ Olúwa sì jẹ aláìlábùkù,gẹ́gẹ́ bí fàdákà ti a yọ́ nínú ìléru àmọ́,tí a sọ di mímọ́ nígbà méje.

7. Olúwa, ìwọ yóò pa wá mọ́kí o sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn ènìyàn wọ̀nyí títí láé.

8. Àwọn ènìyàn búburú ń rin ìrìn fáàrí kirinígbà tí wọn ń bọ̀wọ̀ fún òṣì láàrin àwọn ènìyàn.