“Nítorí ìnilára àwọn aláìlágbáraàti ìkéróra àwọn aláìní,Èmi yóò dìde nísinsin yìí” ni Olúwa wí.“Èmi yóò dáàbò bò wọ́n lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe àrankàn wọn”