orí

  1. 1
  2. 2
  3. 3
  4. 4
  5. 5
  6. 6
  7. 7
  8. 8
  9. 9
  10. 10
  11. 11
  12. 12
  13. 13
  14. 14
  15. 15
  16. 16
  17. 17
  18. 18
  19. 19
  20. 20
  21. 21
  22. 22
  23. 23
  24. 24
  25. 25
  26. 26
  27. 27
  28. 28
  29. 29
  30. 30
  31. 31
  32. 32
  33. 33
  34. 34
  35. 35
  36. 36
  37. 37
  38. 38
  39. 39
  40. 40
  41. 41
  42. 42
  43. 43
  44. 44
  45. 45
  46. 46
  47. 47
  48. 48
  49. 49
  50. 50
  51. 51
  52. 52
  53. 53
  54. 54
  55. 55
  56. 56
  57. 57
  58. 58
  59. 59
  60. 60
  61. 61
  62. 62
  63. 63
  64. 64
  65. 65
  66. 66
  67. 67
  68. 68
  69. 69
  70. 70
  71. 71
  72. 72
  73. 73
  74. 74
  75. 75
  76. 76
  77. 77
  78. 78
  79. 79
  80. 80
  81. 81
  82. 82
  83. 83
  84. 84
  85. 85
  86. 86
  87. 87
  88. 88
  89. 89
  90. 90
  91. 91
  92. 92
  93. 93
  94. 94
  95. 95
  96. 96
  97. 97
  98. 98
  99. 99
  100. 100
  101. 101
  102. 102
  103. 103
  104. 104
  105. 105
  106. 106
  107. 107
  108. 108
  109. 109
  110. 110
  111. 111
  112. 112
  113. 113
  114. 114
  115. 115
  116. 116
  117. 117
  118. 118
  119. 119
  120. 120
  121. 121
  122. 122
  123. 123
  124. 124
  125. 125
  126. 126
  127. 127
  128. 128
  129. 129
  130. 130
  131. 131
  132. 132
  133. 133
  134. 134
  135. 135
  136. 136
  137. 137
  138. 138
  139. 139
  140. 140
  141. 141
  142. 142
  143. 143
  144. 144
  145. 145
  146. 146
  147. 147
  148. 148
  149. 149
  150. 150

Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdúrà Fún Ìdáǹdè Nínú Ìpọ́njú

1. Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, ṣàánú fún mi,nítorí nínú Rẹ ni ààbò ọkàn mí wà.Èmi o fi ààbò mí síbi ìyẹ́ apá Rẹtítí tí ewu yóò fi kọjá lọ.

2. Mo kígbe sókè sí Ọlọ́run gíga jùlọ,sí Ọlọ́run tó ń pa májẹ̀mú Rẹ̀ mọ́ fún mi.

3. Òun yóò ránsẹ́ láti ọ̀run wá,yóò sì gbà mí bí ẹni tí ń fẹ́ gbé mì mìtilẹ̀ ń kẹ́gàn mi.Ọlọ́run yóò rán àánú Rẹ̀ àti òdodo Rẹ̀ jáde.

4. Mo wà ní àárin àwọn kìnnìún;mo dùbúlẹ̀ ni abẹ́ àwọn ẹ̀dá búburúàwọn ènìyàn tí ẹ̀yin wọn dàbí ọ̀kọ̀ àti ọfàẹni tí ahọ́n Rẹ̀ jẹ́ idà mímú.

5. Kí a yìn ọ́ Ọlọ́run, ju ọ̀run lọkí ògo Rẹ kò ju ti gbogbo ayé lọ.

6. Wọn ti ta àwọ̀n sílẹ̀ fún ẹsẹ̀ mi:a tẹ orí ọkàn mi ba nínú ìtìjúwọ́n gbẹ́ kòtò sí ọ̀nà mi:ṣùgbọ́n wọn ti jìn ṣíbẹ̀ fún ara wọn.

7. Ọkàn mi tí múra Ọlọ́run;ọkàn mí ti múra, èmi ó kọrin èmi ó si máa kọrin ìyìn.

8. Jí, ìwọ ọkàn mi!Jí, ohun orin èlò àti dùùrù!Èmi tìkárami, yóò si jí ní kùtùkùtù.

9. Èmi ó máa yín ọ, Olúwa, láàrin àwọn orílẹ̀ èdè;èmi ó máa kọrin sí ọ láàrin àwọn ènìyàn.

10. Nítorí títóbi ní ìfẹ́ Rẹ, tí ó dé ọ̀run;òtítọ́ Rẹ tàn dé àwọ̀sánmọ̀.

11. Gbígbéga ni ọ, Ọlọ́run, ju àwọn ọ̀run lọ;kí ògo Rẹ̀ kí ó ju gbogbo ayé lọ.