1. Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Olúwa, gbogbo ayé
2. Ẹ fi ayọ̀ sin Olúwa:Ẹ wá ṣíwájú Rẹ̀ pẹ̀lú orin dídùn
3. Olúwa Ọlọ́run ni ó dá wa,kí ẹyin kí ó mọ̀ pétirẹ̀ ni àwa; Àwa ní ènìyàn Rẹ̀àti àgùntàn pápá Rẹ̀.
4. Ẹ lọ sí ẹnu ọ̀nà Rẹ̀ pẹlú ọpẹ́àti sí àgbàlá Rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn;ẹ fi ọpẹ́ àti ìyìn fún orúkọ Rẹ̀.
5. Nítorí tí Olúwa pọ̀ ní ooreìfẹ́ Rẹ̀ sì wà títí láé;àti òtítọ́ Rẹ̀ títí dé gbogbo ayé.