orí

  1. 1
  2. 2
  3. 3
  4. 4
  5. 5
  6. 6
  7. 7
  8. 8
  9. 9
  10. 10
  11. 11
  12. 12
  13. 13
  14. 14
  15. 15
  16. 16
  17. 17
  18. 18
  19. 19
  20. 20
  21. 21
  22. 22
  23. 23
  24. 24
  25. 25
  26. 26
  27. 27
  28. 28
  29. 29
  30. 30
  31. 31
  32. 32
  33. 33
  34. 34
  35. 35
  36. 36
  37. 37
  38. 38
  39. 39
  40. 40
  41. 41
  42. 42
  43. 43
  44. 44
  45. 45
  46. 46
  47. 47
  48. 48
  49. 49
  50. 50
  51. 51
  52. 52
  53. 53
  54. 54
  55. 55
  56. 56
  57. 57
  58. 58
  59. 59
  60. 60
  61. 61
  62. 62
  63. 63
  64. 64
  65. 65
  66. 66
  67. 67
  68. 68
  69. 69
  70. 70
  71. 71
  72. 72
  73. 73
  74. 74
  75. 75
  76. 76
  77. 77
  78. 78
  79. 79
  80. 80
  81. 81
  82. 82
  83. 83
  84. 84
  85. 85
  86. 86
  87. 87
  88. 88
  89. 89
  90. 90
  91. 91
  92. 92
  93. 93
  94. 94
  95. 95
  96. 96
  97. 97
  98. 98
  99. 99
  100. 100
  101. 101
  102. 102
  103. 103
  104. 104
  105. 105
  106. 106
  107. 107
  108. 108
  109. 109
  110. 110
  111. 111
  112. 112
  113. 113
  114. 114
  115. 115
  116. 116
  117. 117
  118. 118
  119. 119
  120. 120
  121. 121
  122. 122
  123. 123
  124. 124
  125. 125
  126. 126
  127. 127
  128. 128
  129. 129
  130. 130
  131. 131
  132. 132
  133. 133
  134. 134
  135. 135
  136. 136
  137. 137
  138. 138
  139. 139
  140. 140
  141. 141
  142. 142
  143. 143
  144. 144
  145. 145
  146. 146
  147. 147
  148. 148
  149. 149
  150. 150

Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Olúwa

1. Ìgbẹ́kẹ̀lé mí wà nínú Olúwa.Báwo ní ẹ̀yin o ṣe sọ fún ọkàn mi pé:“Fò gẹ́gẹ́ bi ẹyẹ lọ si orí òkè Rẹ.

2. Wò ó nítorí náà, ènìyàn búburú fa ọfà Rẹ̀;wọn ti ọfà wọn sí ojú okùnláti tafà níbi òjìjìsí àyà ẹni ìdúró ṣinṣin.

3. Nígbà tí ìpìlẹ̀ ba bàjẹ́kí ni olódodo yóò ṣe?”

4. Olúwa ń bẹ nínú tẹ́ḿpìlì mímọ́ Rẹ̀; Olúwa ń bẹ lórí ìtẹ́ Rẹ̀ ní ọ̀run.Ó ń wo àwọn ọmọ ènìyàn;ojú Rẹ̀ ń yẹ̀ wọ́n wò.

5. Olúwa ń yẹ olódodo wò,ṣùgbọ́n ènìyàn búburú àti àwọn tí o fẹ ìwà ipáni ọkàn Rẹ̀ kórìíra.

6. Sí orí àwọn ènìyàn búburú ni yóò rọ̀jòẹ̀yín iná àti ìmí ọjọ́ tí ń jó;àti ìjì gbígbóná ní yóò jẹ ìpín wọn.

7. Nítorí olódodo ní Olúwa,o fẹ́ràn òdodo;ẹni ìdúróṣinṣin yóò sì rí i.