orí

  1. 1
  2. 2
  3. 3
  4. 4
  5. 5
  6. 6
  7. 7
  8. 8
  9. 9
  10. 10
  11. 11
  12. 12
  13. 13
  14. 14
  15. 15
  16. 16
  17. 17
  18. 18
  19. 19
  20. 20
  21. 21
  22. 22
  23. 23
  24. 24
  25. 25
  26. 26
  27. 27
  28. 28
  29. 29
  30. 30
  31. 31
  32. 32
  33. 33
  34. 34
  35. 35
  36. 36
  37. 37
  38. 38
  39. 39
  40. 40
  41. 41
  42. 42

Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 25 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Bilidadi ará Ṣuha bá dáhùn pé,

2. “Ọlọrun ni ọba, òun ló sì tó bẹ̀rù,ó ń ṣe àkóso alaafia lọ́run.

3. Ta ló lè ka àwọn ọmọ ogun rẹ̀?Ta ni ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ kò tàn sí?

4. Báwo wá ni eniyan ṣe lè jẹ́ olódodo níwájú Ọlọrun?Báwo ni ẹni tí obinrin bí ṣe lè jẹ́ ẹni mímọ́?

5. Wò ó, òṣùpá pàápàá kò mọ́lẹ̀ tó,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìràwọ̀ kò mọ́ tó lójú rẹ̀;

6. kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ ti eniyan tí ó dàbí ìdin,tabi ọmọ eniyan tí ó dàbí ekòló lásánlàsàn!”