Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó gbógun tìí yóò máa ṣe bí ó ti wù ú, kò sì sí ẹni tí yóò le è dojú kọ ọ́. Yóò sì fún ara rẹ̀ ní ibùjókòó ní ilẹ̀ tí ó dára, yóò sì ní agbára láti bàá jẹ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:16 ni o tọ