Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò pinnu láti wá pẹ̀lú agbára ìjọba rẹ̀, yóò sì ní májẹ̀mú àlàáfíà pẹ̀lú ọba Gúṣù yóò sì fi ọmọbìnrin rẹ̀ fún-un láti fẹ́ ẹ ní ìyàwó nítorí kí ó lè gba ìjọba, ṣùgbọ́n ète rẹ̀ yìí kì yóò ṣiṣẹ tàbí se ìrànlọ́wọ́ fún-un.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:17 ni o tọ