Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ọba àríwá yóò wá yóò sì gbé ogun tìí, yóò sì kó ìlú olódi. Ogun ọba Gúṣù kò ní ní agbára láti kọjú ìjà sí i; Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọ̀wọ́ ogun tó dára jù kò ní ní agbára láti dúró.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:15 ni o tọ