Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:14-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Nítorí èyí ni a ṣe lé ìdájọ́ òdodo ṣẹ́yìn,àti ti òdodo dúró lókèèrè;òtítọ́ ti ṣubú ní òpópó ọ̀nà,òdodo kò sì le è wọlé.

15. A kò rí òtítọ́ mọ́,àti ẹni tí ó bá sá ibi tì di ìjẹ. Olúwa wò ó ọkàn rẹ̀ sì bàjẹ́pé kò sí ìdájọ́ òdodo.

16. Òun rí i pé kò sí ẹnìkan,àyà fò ó pé kò sí ẹnìkan láti ṣèrànwọ́;nítorí apá òun tìkálárarẹ̀ ló ṣiṣẹ́ ìgbàlà fún ara rẹ̀,àti òdodo òun tìkálára rẹ̀ ló gbé e ró.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59