Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ọ̀tẹ̀ àti àrékérekè wa sí Olúwa,kíkọ ẹ̀yìn wa sí Ọlọ́run,dídá yánpọnyánrin àti ìnilára sílẹ̀,pípààrọ̀ tí ọkàn wa ti gbérò síta.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:13 ni o tọ