Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun rí i pé kò sí ẹnìkan,àyà fò ó pé kò sí ẹnìkan láti ṣèrànwọ́;nítorí apá òun tìkálárarẹ̀ ló ṣiṣẹ́ ìgbàlà fún ara rẹ̀,àti òdodo òun tìkálára rẹ̀ ló gbé e ró.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:16 ni o tọ