Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé òdodo wọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàya rẹ̀,àti àsíborí ìgbàlà ní oríi rẹ̀;ó gbé ẹ̀wù ẹ̀san wọ̀ó sì yí ara rẹ̀ ní ìtara bí ẹ̀wù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:17 ni o tọ