Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 5:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikan ba si ṣẹ̀, ti o ba si ṣe ọkan ninu nkan wọnyi, eyiti ofin OLUWA kọ̀ lati ṣe; bi kò tilẹ mọ̀, ṣugbọn o jẹbi, yio si rù ẹ̀ṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Lef 5

Wo Lef 5:17 ni o tọ