Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 5:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si ṣe atunṣe nitori ibi ti o ti ṣe ninu ohun mimọ́, ki o si fi idamarun pẹlu rẹ̀, ki o si fi i fun alufa: alufa yio si fi àgbo ẹbọ ẹ̀ṣẹ na ṣètutu fun u, a o si dari rẹ̀ jì i.

Ka pipe ipin Lef 5

Wo Lef 5:16 ni o tọ