Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 5:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si mú àgbo kan alailabùku lati inu agbo-ẹran tọ̀ alufa wá ni idiyele rẹ, fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ: ki alufa ki o si ṣètutu fun u nitori aimọ̀ rẹ̀ ninu eyiti o ṣìṣe ti kò si mọ̀, a o si dari rẹ̀ jì i.

Ka pipe ipin Lef 5

Wo Lef 5:18 ni o tọ