Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 1:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elkana ọkọ rẹ̀ si wi fun u pe, Ṣe eyi ti o tọ li oju rẹ; duro titi iwọ o fi gba ọmu li ẹnu rẹ̀; ṣugbọn ki Oluwa ki o sa mu ọ̀rọ rẹ̀ ṣẹ. Bẹ̃li obinrin na si joko, o si fi ọmu fun ọmọ rẹ̀ titi o fi gbà a lẹnu rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 1

Wo 1. Sam 1:23 ni o tọ