Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 1:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Hanna ko goke lọ; nitori ti o wi fun ọkọ rẹ̀ pe, o di igbati mo ba gba ọmu lẹnu ọmọ na, nigbana li emi o mu u lọ, ki on ki o le fi ara han niwaju Oluwa, ki o si ma gbe ibẹ titi lai.

Ka pipe ipin 1. Sam 1

Wo 1. Sam 1:22 ni o tọ