Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 1:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si gba ọmu li ẹnu rẹ̀, o si mu u goke lọ pẹlu ara rẹ̀, pẹlu ẹgbọrọ malu mẹta, ati iyẹfun efa kan, ati igo ọti-wain kan, o si mu u wá si ile Oluwa ni Ṣilo: ọmọ na si wà li ọmọde.

Ka pipe ipin 1. Sam 1

Wo 1. Sam 1:24 ni o tọ