Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kì í ṣe nítorí pé Abrahamu pa Òfin mọ́ ni Ọlọrun fi ṣe ìlérí fún òun ati ìran rẹ̀ pé yóo jogún ayé; nítorí ó gba Ọlọrun gbọ́ ni, Ọlọrun sì kà á sí ẹni rere.

Ka pipe ipin Romu 4

Wo Romu 4:13 ni o tọ