Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì di baba fún àwọn tí ó kọlà ṣugbọn tí wọn kò gbẹ́kẹ̀lé ilà tí wọ́n kọ, ṣugbọn tí wọn ń rìn ní irú ọ̀nà igbagbọ tí baba wa Abrahamu ní kí ó tó kọlà.

Ka pipe ipin Romu 4

Wo Romu 4:12 ni o tọ