Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí bí ó bá jẹ́ pé àwọn tí ń tẹ̀lé ètò Òfin ni yóo jogún ìlérí Ọlọrun, a jẹ́ pé ọ̀ràn àwọn tí ó dúró lórí igbagbọ di òfo, ìlérí Ọlọrun sì di òtúbáńtẹ́.

Ka pipe ipin Romu 4

Wo Romu 4:14 ni o tọ