Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá pe àwọn ará Gibeoni, ó sì bi wọ́n pé, “Kí ni ẹ fẹ́ kí n ṣe fun yín? Ọ̀nà wo ni mo lè gbà ṣe àtúnṣe ibi tí wọ́n ṣe si yín, kí ẹ baà lè súre fún àwọn eniyan OLUWA?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:3 ni o tọ