Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Aáwọ̀ tí ó wà láàrin àwa ati Saulu ati ìdílé rẹ̀, kì í ṣe ohun tí a lè fi wúrà ati fadaka parí, a kò sì fẹ́ pa ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ Israẹli.”Dafidi bá tún bèèrè pé, “Kí ni ẹ wá fẹ́ kí n ṣe fun yín?”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:4 ni o tọ