Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 30:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan ti wù kí ó ní owó tó, kò gbọdọ̀ san ju ìdajì ṣekeli kan lọ; bí ó sì ti wù kí eniyan tòṣì tó, kò gbọdọ̀ san dín ní ìdajì ṣekeli kan, nígbà tí ẹ bá ń san ọrẹ OLUWA fún ìràpadà ẹ̀mí yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:15 ni o tọ