Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 30:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni tí a bá kà ní àkókò ìkànìyàn náà, tí ó bá tó ọmọ ogún ọdún tabi jù bẹ́ẹ̀ lọ, ó gbọdọ̀ san owó náà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:14 ni o tọ