Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 30:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Gba owó ètùtù lọ́wọ́ àwọn eniyan Israẹli, kí o sì máa lò ó fún iṣẹ́ ilé ìsìn àgọ́ àjọ, kí ó lè máa mú àwọn ọmọ Israẹli wá sí ìrántí níwájú OLUWA, kí ó sì lè jẹ́ ètùtù fún yín.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:16 ni o tọ