Sí Títù, ọmọ mi tòótọ́ nínú ìgbàgbọ́ wa kan náà.Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run baba àti Kírísítì Jésù Olùgbàlà wa.