Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí tí mo fi fi ọ́ sílẹ̀ ní Kírétè ni pé kí o lè ṣe àsepé àwọn iṣẹ́ tó sẹ́kù. Mo sì ń rọ̀ ọ́ kí o yan àwọn alàgbà ní ìlú kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí mo ṣe darí rẹ̀.

Ka pipe ipin Títù 1

Wo Títù 1:5 ni o tọ