Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti pé ní àkókò tirẹ̀, òun ti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ hàn nínú ìwàásù tí a fi lé mi lọ́wọ́ nípa àṣẹ Ọlọ́run Olùgbàlà wa.

Ka pipe ipin Títù 1

Wo Títù 1:3 ni o tọ