Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 15:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú ayọ̀ ni wọ́n ń se èyí, nítorí wọ́n gbà wí pé, wọ́n jẹ́ ajigbésè fún wọn. Nítorí bí ó bá se pé a fi àwọn aláìkọlà se alájọni nínú ohun ẹ̀mí wọn, ajigbèsè sì ni wọn láti fi ohun ti ara ta wọ́n lọ́rẹ.

Ka pipe ipin Róòmù 15

Wo Róòmù 15:27 ni o tọ