Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 15:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, nígbà tí mo bá ti se èyí tán tí mo bá sì di ẹ̀dìdì èso náà fún wọn tán, èmi yóò gba ti ọ̀dọ̀ yín bí mo bá ń lọ sí orílẹ̀ èdè Sípáníà.

Ka pipe ipin Róòmù 15

Wo Róòmù 15:28 ni o tọ