Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wí pé, “Òun yóò pa àwọn ènìyàn búburú náà run, ní ipò òsì, yóò sì fi ọgbà àjàrà rẹ̀ fún àwọn alágbàtọ́jú mìíràn tí yóò fún un ní èso tirẹ̀ lásìkò ìkórè.”

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:41 ni o tọ