Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún wọ́n pé, “Àbí ẹ̀yin kò kà á nínú ìwé Mímọ́ pé:“ ‘Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀,ni ó di pàtàkì igun ilé;Iṣẹ́ Olúwa ni èyí,ó sì jẹ́ ìyanu ní ojú wa’?

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:42 ni o tọ