Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Jòhánù tọ́ yin wá láti fi ọ̀nà òdodo hàn yín, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò gbà á gbọ́, ṣùgbọ́n àwọn agbowó-òde àti àwọn panṣágà ronúpìwàdà, bí ó tilẹ̀ ṣe pé ẹ rí àwọn ohun tí ń ṣẹlẹ̀ wọ̀nyí, ẹ kọ̀ láti ronúpìwàdà, ẹ kò gbà á gbọ́.”

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:32 ni o tọ