Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nínú àwọn méjèèjì yìí, èwo ni ó ṣe ìfẹ́ baba wọn?”Gbogbo wọn sì fohùn ṣọ̀kan pé, “Èyí ẹ̀gbọ́n ni.”Jésù wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, àwọn agbowó-òde àti àwọn panṣágà yóò wọ ìjọba ọ̀run ṣíwájú yín.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:31 ni o tọ