Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ gbọ́ òwe mìíràn: Baálé ilé kan tí ó gbin àjàrà, ó ṣe ọgbà yìí ká, ó wá ibi ifúntí sínú rẹ̀, ó kọ́ ilé-ìsọ́. Ó sì fi oko náà ṣe àgbàtọ́jú fún àwọn àgbẹ̀ kan, ó sì lọ sí ìrìnàjò.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:33 ni o tọ