Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì sí ẹni tí ń fi ọtí wáìnì túntún sínú ìgò wáìni ògbólógbó. Bí a bá ṣe bẹ́ẹ̀, ọtí wáìnì náà yóò fa ìgò náà ya, ọtí wáìnì a si dàànu, bákan náà ni ìgò náà, ṣùgbọ́n ọtí wáìnì tuntun ni a n fi sínú ìgò wáìnì tuntun.”

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:22 ni o tọ