Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò si ẹni tí ń fi ìrépé aṣọ túntún lẹ ògbólógbo ẹ̀wù, bí ó ba se bẹ́ẹ̀, èyí túntún ti a fi lẹ̀ ẹ́ yóò fà ya kúrò lára ògbólógbòó, yíyọ́ rẹ̀ yóò sí burú púpọ̀ jù.

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:21 ni o tọ