Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe ni ọjọ ìsinmi, bí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti ń kọjá lọ láàrin oko ọkà, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í ya ìpẹ́ ọká.

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:23 ni o tọ