Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 15:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Àwọn ọmọ-ogun sì fà á jáde lọ sínú gbangba (tí a ń pè ní Piretorioni), wọ́n sì pe gbogbo ẹgbẹ́ àwọn ọmọ ogun jọ.

17. Wọn sì fi aṣọ aláwọ̀ àlùkò wọ̀ ọ́, wọ́n hun adé ẹ̀gún, wọ́n sì fi dé e ní orí.

18. Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí i kí ì, wí pé Kábíyèsí, Ọba àwọn Júù

Ka pipe ipin Máàkù 15