Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pilatù sì ń fẹ́ se èyí tí ó wu àwọn ènìyàn, ó dá Bárábà sílẹ̀ fún wọn. Nígbà tí ó sì na Jésù tan o fà á lé wọn lọ́wọ́ láti kàn an mọ́ àgbélébùú.

Ka pipe ipin Máàkù 15

Wo Máàkù 15:15 ni o tọ