Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi ọ̀pá ìyè lù ú lórí, wọ́n sì tutọ́ síi lára, wọ́n sì kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n sì foríbalẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Máàkù 15

Wo Máàkù 15:19 ni o tọ