Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 13:35-37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

35. “Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́, ẹ̀yin pẹ̀lú ní láti máa fi ìrètí sọ́nà, nítorí pé ẹ kò mọ àkókò tí baálé ilé yóò da. Bóyá ní ìrọ̀lẹ́ ni o, tàbí ní ọ̀gànjọ́ òru, tàbí nígbà tí àkùkọ máa ń kọ, tàbí ní òwúrọ̀.

36. Pé nígbà tí bá dé lójijì, kó má ṣe bá yín lójú oorun.

37. Ohun tí mo wí fún un yín, mo wí ì fuń gbogbo ènìyàn: ‘Ẹ máa ṣọ́nà!’ ”

Ka pipe ipin Máàkù 13