Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí a lè fi bíbọ̀ mi wé ni ọkùnrin kan tí ó lọ sí ìrìnàjò sí orílẹ̀ èdè mìíràn. Kí ó tó lọ, ó pín iṣẹ́ fún àwọn tí ó gbà ṣíṣẹ́, àní, iṣẹ́ tí ẹnìkọ̀ọ̀kan yóò ṣe nígbà tí ó bá lọ, ó ní kí ọ̀kan nínú wọn dúró lẹ́nu-ọ̀nà láti máa ṣọ́nà títí òun yóò fi dé.

Ka pipe ipin Máàkù 13

Wo Máàkù 13:34 ni o tọ