Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 13:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́, ẹ̀yin pẹ̀lú ní láti máa fi ìrètí sọ́nà, nítorí pé ẹ kò mọ àkókò tí baálé ilé yóò da. Bóyá ní ìrọ̀lẹ́ ni o, tàbí ní ọ̀gànjọ́ òru, tàbí nígbà tí àkùkọ máa ń kọ, tàbí ní òwúrọ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 13

Wo Máàkù 13:35 ni o tọ