Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ọkùnrin tí ó fi ọkàn rán ìdẹwò; nítorí nígbà tí ó bá yege, yóò gba adé ìyè, tí Olúwa ti ṣèlérí fún àwọn tí ó fẹ́ ẹ.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 1

Wo Jákọ́bù 1:12 ni o tọ