Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹnikẹ́ni tí a dẹwò kí ó má ṣe wí pé, “Láti ọwọ́ Ọlọ́run ni a ti dán mi wò.” Nítorí a kò lè fi búburú dán Ọlọ́run wò, òun náà kì í sì í dán ẹnìkẹ́ni wò;

Ka pipe ipin Jákọ́bù 1

Wo Jákọ́bù 1:13 ni o tọ