Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí oòrùn là ti òun ti ooru mímú ó sì gbẹ́ koríko, ìtànná rẹ̀ sì rẹ̀ dànú, ẹwà ojú rẹ̀ sì parun: bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ni ọlọ́rọ̀ yóò ṣègbé ní ọ̀nà rẹ̀.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 1

Wo Jákọ́bù 1:11 ni o tọ