Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní wákàtí náà ìmìmì-ilẹ̀ ńlá kan sì mì, ìdámẹ̀wàá ìlú náà sì wó, àti nínú ìmìmì-ilẹ̀ náà ẹ̀ẹ́dẹ́gbàárin ènìyàn ní a pa; ẹ̀rù sì ba àwọn ìyókù, wọn sì fi ògo fún Ọlọ́run ọ̀run.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:13 ni o tọ